

소개
EWI S??R?? SO?KE?: O j?? ohun idunnu fun mi pup?? lati k? iwe akoj?p?? ewi yii. Aw?n ewi j? ohun abalaye ti o j? ?m? Yoruba logun. Ni aye atij?? ni ile Yoruba, o un ni aw?n baba-?la wa maa ? lo fun imo?, imo?ran ati ??k??, ?ugbo?n won kii k??? sil?? nitori pe, w?n ko ni imo? mo?o?k?-mo?o?ka rara. Orisirisi aw?n ewi ni o wa, Ero ?kan mi ni pe a o gbadun iwe akoj?p?? ewi yii. "Ewi S??r?? Soke!" ni ak?le Iwe I?ipaya Ewi Yoruba yii (Poetry On Speak Up!).



